ترانه و شعر با صدای Ayo Maff
Congratulation l'orin ta maa kọ ọ-ọ (Decs, motherf-f-f-)
You fit get money make you no get sense o Gbo-gbo owo ta ma pa, what is the essence o? Ah, ti n ba ku, ṣe owo le ji mi dide? Ah, ti n ba ku, ṣe owo le ji mi dide? Personal vendetta, I've been fighting sapa Mo ṣiṣẹ, mo ṣiṣẹ, ọmọ oro mi, mo sapa Ọjọ ti mi kọkọ ri one million, mo sunkun Alẹ ọjọ yẹn no ni solo ku, mo tun sunkun
On that day, me, I go dey Ṣe you go dey? Ṣe you go dey? Congratulation l'orin ta maa kọ Congratulation l'orin ta maa kọ ọ (ori mi)
Emi lo mi, ẹ gbọmọ lẹyin mi B'ọmọba n ke, ẹ gbe fun Iya Dada Miliki yaya, Bournvita yaya
Mi o le ṣe ogun owo Mi o le ṣe ogun owo But to ba gb'ọṣẹ fun mi Mo le wẹ ki n le jo Olowo ye bi Ọlọrun, calm down Iwọ kọ lo da mi, o le pa mi
Oble, oble, oble ni mo sọ Ninu two dollar awọn temi sing along Aṣabi ṣa dollar, ọmọ owo ṣa pounds To ba fun mi good strains Ọmọ, mo ma ra ounce Olomi, dari ji mi, dari ji mi o Olomi, dari ji mi, dari ji mi o Ibadi aran, Mosunmọla, maa ba mi ja ah
On that day, me, I go dey Ṣe you go dey? Ṣe you go dey? Congratulation l'orin ta maa kọ Congratulation l'orin ta maa kọ ọ
Emi lo mi, ẹ gbọmọ lẹyin mi B'ọmọba n ke, ẹ gbe fun Iya Dada Miliki yaya, Bournvita yaya
(Motherf-f-f-)
آثار دیگر از Ayo Maff